Joṣua 10:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Joṣua ati gbogbo àwọn ọmọ Israẹli bá gbéra láti Libina lọ sí Lakiṣi. Wọ́n dó tì í, wọ́n sì bá a jagun.

Joṣua 10

Joṣua 10:26-36