Joṣua 10:21 BIBELI MIMỌ (BM)

gbogbo àwọn eniyan pada sọ́dọ̀ Joṣua ní àgọ́ tí ó wà ní Makeda láìsí ewu.Kò sì sí ẹni tí ó sọ ìsọkúsọ sí àwọn ọmọ Israẹli.

Joṣua 10

Joṣua 10:17-23