Joṣua 1:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Múra, kí o sì ṣe ọkàn gírí, nítorí ìwọ ni o óo jẹ́ kí àwọn eniyan wọnyi gba ilẹ̀ tí mo ti búra fún àwọn baba wọn, pé n óo fún wọn.

Joṣua 1

Joṣua 1:1-11