Joṣua 1:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ibi tí ẹsẹ̀ yín bá tẹ̀ ni mo ti fun yín, gẹ́gẹ́ bí mo ti ṣèlérí fún Mose.

Joṣua 1

Joṣua 1:1-4