Joṣua 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ ranti àṣẹ tí Mose, iranṣẹ OLUWA, pa fun yín pé, ‘OLUWA Ọlọrun yín ń pèsè ibi ìsinmi fun yín, yóo sì fi ilẹ̀ yìí fun yín.’

Joṣua 1

Joṣua 1:6-14