Jona 4:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ǹjẹ́ nisinsinyii, OLUWA, mo bẹ̀ ọ́, gba ẹ̀mí mi, nítorí pé, ó sàn fún mi láti kú ju pé kí n wà láàyè lọ.”

Jona 4

Jona 4:1-11