Jona 3:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Ọlọrun rí i pé wọ́n ti pa ìwà burúkú wọn tì, Ọlọrun náà bá yí ìpinnu rẹ̀ pada, kò sì jẹ wọ́n níyà mọ́.

Jona 3

Jona 3:7-10