Jona 2:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Jona gbadura sí OLUWA Ọlọrun rẹ̀ láti inú ẹja náà,

2. ó ní, “Ninu ìpọ́njú mi, mo ké pe OLUWA,ó sì dá mi lóhùn,mo ké pè é láti inú isà òkú, ó sì gbóhùn mi.

Jona 2