Johanu 9:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Farisi wà láàrin àwọn eniyan tí ó wà pẹlu rẹ̀, tí ó gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí. Wọ́n bi í pé, “Àbí àwa náà fọ́jú?”

Johanu 9

Johanu 9:35-41