Johanu 9:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu gbọ́ pé wọ́n ti ti ọkunrin náà jáde kúrò ninu ilé ìpàdé. Nígbà tí ó rí i, ó bí i pé, “Ìwọ gba Ọmọ-Eniyan gbọ́ bí?”

Johanu 9

Johanu 9:29-41