Johanu 9:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí bú u, wọ́n ní, “Ìwọ ni ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, ní tiwa, ọmọ-ẹ̀yìn Mose ni wá.

Johanu 9

Johanu 9:22-30