Johanu 9:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn Farisi tún bi ọkunrin náà bí ó ti ṣe ríran. Ó sọ fún wọn pé, “Ó lẹ amọ̀ mọ́ mi lójú, mo lọ bọ́jú, mo bá ríran.”

Johanu 9

Johanu 9:13-19