Johanu 8:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn amòfin ati àwọn Farisi mú obinrin kan wá, tí wọ́n ká mọ́ ibi tí ó ti ń ṣe àgbèrè. Wọ́n ní kí ó dúró láàrin wọn;

Johanu 8

Johanu 8:2-8