Johanu 8:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bi í pé, “Níbo ni baba rẹ wà?”Jesu dá wọn lóhùn pé, “Ẹ kò mọ̀ mí, bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò mọ Baba mi. Bí ó bá jẹ́ pé ẹ mọ̀ mí, ẹ̀ bá mọ Baba mi.”

Johanu 8

Johanu 8:9-20