Johanu 7:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí wá ọ̀nà láti mú un, ṣugbọn ẹnikẹ́ni kò fi ọwọ́ kàn án nítorí àkókò rẹ̀ kò ì tíì tó.

Johanu 7

Johanu 7:25-39