Johanu 7:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnu ya àwọn Juu, wọ́n ń sọ pé, “Báwo ni eléyìí ti ṣe mọ ìwé tó báyìí nígbà tí kò lọ sí ilé-ìwé?”

Johanu 7

Johanu 7:12-20