Johanu 7:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí àwọn arakunrin Jesu ti lọ sí ibi àjọ̀dún náà, òun náà wá lọ. Ṣugbọn, kò lọ ní gbangba, yíyọ́ ni ó yọ́ lọ.

Johanu 7

Johanu 7:5-19