Johanu 6:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Filipi dá a lóhùn pé, “Burẹdi igba owó fadaka kò tó kí ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn lè fi rí díẹ̀díẹ̀ panu!”

Johanu 6

Johanu 6:1-12