Johanu 6:68 BIBELI MIMỌ (BM)

Simoni Peteru dá a lóhùn pé, “Oluwa, ọ̀dọ̀ ta ni à bá lọ? Ìwọ ni o ní ọ̀rọ̀ ìyè ainipẹkun.

Johanu 6

Johanu 6:60-70