Johanu 6:65 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Nítorí èyí ni mo ṣe sọ fun yín pé kò sí ẹni tí ó lè wá sọ́dọ̀ mi, àfi bí Baba mi bá ṣí ọ̀nà fún un láti wá.”

Johanu 6

Johanu 6:58-71