Johanu 6:60 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọpọlọpọ tí ó gbọ́ ninu àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sọ pé, “Ọ̀rọ̀ yìí le, kò sí ẹni tí ó lè gba irú rẹ̀!”

Johanu 6

Johanu 6:51-67