Johanu 6:54 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó bá jẹ ẹran-ara mi, tí ó sì mu ẹ̀jẹ̀ mi, ní ìyè ainipẹkun, èmi yóo sì jí i dìde ní ọjọ́ ìkẹyìn.

Johanu 6

Johanu 6:45-59