Johanu 6:50 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn oúnjẹ tí ó ń ti ọ̀run sọ̀kalẹ̀ ni èyí tí ó jẹ́ pé bí ẹnìkan bá jẹ ninu rẹ̀, olúwarẹ̀ kò ní kú.

Johanu 6

Johanu 6:47-60