Johanu 6:44 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sí ẹni tí ó lè wá sọ́dọ̀ mi àfi bí Baba tí ó rán mi níṣẹ́ bá fà á wá, èmi óo wá jí i dìde ní ọjọ́ ìkẹyìn.

Johanu 6

Johanu 6:35-53