Johanu 6:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ẹni tí Baba ti fi fún mi yóo wá sọ́dọ̀ mi. Ẹnikẹ́ni tí ó bá wá sọ́dọ̀ mi, n kò ní ta á nù;

Johanu 6

Johanu 6:32-44