Johanu 6:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn baba wa jẹ mana ní aṣálẹ̀, gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ pé, ‘Ó fún wọn ní oúnjẹ láti ọ̀run wá jẹ.’ ”

Johanu 6

Johanu 6:26-32