Johanu 6:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu bá gun orí òkè lọ, ó jókòó níbẹ̀ pẹlu àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀.

Johanu 6

Johanu 6:1-10