Johanu 6:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá fi tayọ̀tayọ̀ gbà á sinu ọkọ̀. Lẹsẹkẹsẹ ọkọ̀ sì gúnlẹ̀ sí ibi tí wọn ń lọ.

Johanu 6

Johanu 6:16-26