Johanu 6:17 BIBELI MIMỌ (BM)

wọ́n wọ ọkọ̀, wọ́n ń lọ sí Kapanaumu ní òdìkejì òkun. Òkùnkùn ti ṣú ṣugbọn Jesu kò ì tíì dé ọ̀dọ̀ wọn.

Johanu 6

Johanu 6:11-18