Johanu 6:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu ní, “Ẹ ní kí wọ́n jókòó.” Koríko pọ̀ níbẹ̀. Àwọn eniyan náà bá jókòó. Wọ́n tó bí ẹgbẹẹdọgbọn (5,000).

Johanu 6

Johanu 6:2-17