Johanu 5:45 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ má ṣe rò pé èmi ni n óo fi yín sùn níwájú Baba, Mose tí ẹ gbẹ́kẹ̀lé gan-an ni yóo fi yín sùn.

Johanu 5

Johanu 5:38-46