Johanu 5:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi wá ní orúkọ Baba mi, ẹ̀yin kò gbà mí. Ṣugbọn bí ẹlòmíràn bá wá ní orúkọ ara rẹ̀, ẹ óo gbà á.

Johanu 5

Johanu 5:34-47