Johanu 5:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Kì í ṣe pé dandan ni fún mi pé kí eniyan jẹ́rìí gbè mí. Ṣugbọn mo sọ èyí fun yín kí ẹ lè ní ìgbàlà.

Johanu 5

Johanu 5:29-43