Johanu 5:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ti fún un ní àṣẹ láti ṣe ìdájọ́, nítorí òun ni Ọmọ-Eniyan.

Johanu 5

Johanu 5:21-34