Johanu 5:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Jesu dá wọn lóhùn pé, “Baba mi ń ṣiṣẹ́ títí di ìsinsìnyìí, èmi náà sì ń ṣiṣẹ́.”

Johanu 5

Johanu 5:13-18