Johanu 5:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ọkunrin náà tí Jesu wòsàn kò mọ ẹni tí ó wo òun sàn, nítorí pé eniyan pọ̀ níbẹ̀, ati pé Jesu ti yẹra kúrò níbẹ̀.

Johanu 5

Johanu 5:6-22