Johanu 4:46 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu tún lọ sí ìlú Kana ti Galili níbi tí ó ti sọ omi di ọtí ní ìjelòó. Ìjòyè kan wà ní Kapanaumu tí ọmọ rẹ̀ ń ṣàìsàn.

Johanu 4

Johanu 4:45-54