Johanu 4:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu wí fún wọn pé, “Ní tèmi, oúnjẹ mi ni láti ṣe ìfẹ́ ẹni tí ó rán mi níṣẹ́ ati láti parí iṣẹ́ tí ó fún mi ṣe.

Johanu 4

Johanu 4:26-44