Johanu 4:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ará Samaria kò mọ ẹni tí ẹ̀ ń sìn. Àwa Juu mọ ẹni tí à ń sìn, nítorí láti ọ̀dọ̀ wa ni ìgbàlà ti wá.

Johanu 4

Johanu 4:13-26