Johanu 4:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní orí òkè tí ó wà lọ́hùn-ún yìí ni àwọn baba wa ń sin Ọlọrun, ṣugbọn ẹ̀yin wí pé Jerusalẹmu ni ibi tí a níláti máa sìn ín.”

Johanu 4

Johanu 4:14-26