Johanu 3:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nikodemu bi í pé, “Báwo ni a ti ṣe lè tún ẹni tí ó ti di àgbàlagbà bí? Kò sá tún lè pada wọ inú ìyá rẹ̀ lẹẹkeji kí á wá tún un bí!”

Johanu 3

Johanu 3:1-6