Johanu 3:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí Ọlọrun kò rán Ọmọ rẹ̀ wá sí ayé láti dá aráyé lẹ́bi bíkòṣe pé kí aráyé lè ti ipasẹ̀ rẹ̀ ní ìgbàlà.

Johanu 3

Johanu 3:11-19