Johanu 3:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo fẹ́ kí o mọ̀ dájúdájú pé, à ń sọ ohun tí a mọ̀, a sì ń jẹ́rìí ohun tí a rí, ṣugbọn ẹ̀yin kò gba ẹ̀rí wa.

Johanu 3

Johanu 3:4-21