Johanu 3:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin kan wà ninu àwọn Farisi tí ń jẹ́ Nikodemu. Ó jẹ́ ọ̀kan ninu ìgbìmọ̀ àwọn Juu.

Johanu 3

Johanu 3:1-10