Johanu 21:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Simoni Peteru sọ fún wọn pé, “Mò ń lọ pa ẹja.”Wọ́n dá a lóhùn pé, “Àwa náà yóo bá ọ lọ.” Wọ́n bá jáde lọ, wọ́n wọ ọkọ̀ ojú omi. Ní gbogbo alẹ́ ọjọ́ náà wọn kò rí ẹja kankan pa.

Johanu 21

Johanu 21:2-8