Johanu 21:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọmọ-ẹ̀yìn náà ni ó jẹ́rìí sí nǹkan wọnyi. Òun ni ó kọ nǹkan wọnyi: a mọ̀ pé òtítọ́ ni ẹ̀rí rẹ̀.

Johanu 21

Johanu 21:18-25