Johanu 21:19 BIBELI MIMỌ (BM)

(Jesu sọ èyí bí àkàwé irú ikú tí Peteru yóo fi yin Ọlọrun lógo.) Nígbà tí Jesu sọ báyìí tán, ó wí fún un pé, “Máa tẹ̀lé mi.”

Johanu 21

Johanu 21:10-25