Johanu 21:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu tún bi í lẹẹkeji pé, “Simoni ọmọ Johanu, ǹjẹ́ o fẹ́ràn mi?”Ó tún dá a lóhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni Oluwa, o mọ̀ pé mo fẹ́ràn rẹ.”Jesu wí fún un pé, “Máa tọ́jú àwọn aguntan mi.”

Johanu 21

Johanu 21:6-23