Johanu 21:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn èyí, Jesu tún fara han àwọn ọmọ-ẹ̀yìn ní òkun Tiberiasi. Bí ó ṣe farahàn wọ́n nìyí:

Johanu 21

Johanu 21:1-4