Johanu 20:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn mejeeji bẹ̀rẹ̀ sí sáré; ṣugbọn ọmọ-ẹ̀yìn keji ya Peteru sílẹ̀, òun ni ó kọ́ dé ibojì.

Johanu 20

Johanu 20:1-5